O jọ pe igbesunmọmi, ikọlu ati rogbodiyan to maa n waye lapa Ariwa Naijiria ti gba ọna mi-in yọ , pẹlu gbajare tuntun to jade lati ẹnu minisita ọrọ abẹle tẹle to tun jẹ ológun, Ajagunfẹyinti ...
Awọn to n ṣagbatẹru idasilẹ Yoruba nation ti ṣalaye fun ijọba Naijiria pe ẹgbẹ ajijagbara IPOB kọ lo ṣe agbekalẹ ifẹhonuhan tawọn n ṣe ni olu ileeṣẹ ajọ iṣọkan agbaye, UN lorilẹede Amẹrika. Eyi ni esi ...